Sáàmù 34:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ tọ́ ọ wò, kí ẹ sì rí i pé ẹni rere ni Jèhófà,+Aláyọ̀ ni ọkùnrin tí ó fi í ṣe ibi ààbò. Òwe 13:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àjálù kì í dẹ̀yìn lẹ́yìn àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀,+Àmọ́ aásìkí ni èrè àwọn olódodo.+ Òwe 16:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹni tó ń lo ìjìnlẹ̀ òye nínú ọ̀ràn yóò ṣàṣeyọrí,*Aláyọ̀ sì ni ẹni tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà.