Jóṣúà 11:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí náà, Jèhófà sọ fún Jóṣúà pé: “Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù wọn bà ọ́,+ torí ní ìwòyí ọ̀la, màá fi gbogbo wọn lé Ísírẹ́lì lọ́wọ́ láti pa wọ́n. Kí o já iṣan ẹsẹ̀*+ àwọn ẹṣin wọn, kí o sì dáná sun àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn.”
6 Torí náà, Jèhófà sọ fún Jóṣúà pé: “Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù wọn bà ọ́,+ torí ní ìwòyí ọ̀la, màá fi gbogbo wọn lé Ísírẹ́lì lọ́wọ́ láti pa wọ́n. Kí o já iṣan ẹsẹ̀*+ àwọn ẹṣin wọn, kí o sì dáná sun àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn.”