Sáàmù 37:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Láìpẹ́, àwọn ẹni burúkú ò ní sí mọ́;+ Wàá wo ibi tí wọ́n wà tẹ́lẹ̀,Wọn ò ní sí níbẹ̀.+ Òwe 10:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìrántí* olódodo yẹ fún ìbùkún,+Àmọ́ orúkọ àwọn ẹni burúkú yóò jẹrà.+