ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 25:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 Nígbà tí Dáfídì gbọ́ pé Nábálì ti kú, ó sọ pé: “Ẹ yin Jèhófà, ẹni tí ó bá mi dá ẹjọ́ mi+ nítorí àbùkù tí Nábálì fi kàn mí,+ tí kò sì jẹ́ kí ìránṣẹ́ rẹ̀ ṣe ohun búburú,+ Jèhófà sì ti mú kí ibi Nábálì dà lé e lórí!” Dáfídì wá ránṣẹ́ sí Ábígẹ́lì pé kó wá di ìyàwó òun.

  • Sáàmù 52:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 O nífẹ̀ẹ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń pani run,

      Ìwọ ahọ́n ẹ̀tàn!

       5 Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run yóò fi mú ọ balẹ̀ láìtún gbérí mọ́;+

      Yóò gbá ọ mú, yóò sì fà ọ́ kúrò nínú àgọ́ rẹ;+

      Yóò fà ọ́ tu kúrò ní ilẹ̀ alààyè.+ (Sélà)

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́