Àìsáyà 42:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà máa jáde lọ bí akíkanjú ọkùnrin.+ Ó máa mú kí ìtara rẹ̀ sọjí bíi ti jagunjagun.+ Ó máa kígbe, àní, ó máa kígbe ogun;Ó máa fi hàn pé òun lágbára ju àwọn ọ̀tá òun lọ.+
13 Jèhófà máa jáde lọ bí akíkanjú ọkùnrin.+ Ó máa mú kí ìtara rẹ̀ sọjí bíi ti jagunjagun.+ Ó máa kígbe, àní, ó máa kígbe ogun;Ó máa fi hàn pé òun lágbára ju àwọn ọ̀tá òun lọ.+