-
Sáàmù 57:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Wọ́n ti gbẹ́ kòtò dè mí,
Àmọ́ àwọn fúnra wọn kó sínú rẹ̀.+ (Sélà)
-
-
Sáàmù 141:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àwọn ẹni burúkú lápapọ̀ yóò já sínú àwọ̀n tí àwọn fúnra wọn dẹ,+
Èmi á sì kọjá lọ láìséwu.
-