Sáàmù 27:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Má fi mí lé ọwọ́ àwọn elénìní mi,*+Nítorí pé àwọn ẹlẹ́rìí èké ti dìde sí mi,+Wọ́n sì ń halẹ̀ pé àwọn máa ṣe mí léṣe. Mátíù 26:59 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 59 Àwọn olórí àlùfáà àti gbogbo Sàhẹ́ndìrìn ń wá ẹ̀rí èké tí wọ́n máa fi mú Jésù kí wọ́n lè pa á.+
12 Má fi mí lé ọwọ́ àwọn elénìní mi,*+Nítorí pé àwọn ẹlẹ́rìí èké ti dìde sí mi,+Wọ́n sì ń halẹ̀ pé àwọn máa ṣe mí léṣe.