Sáàmù 73:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí mo jowú àwọn agbéraga*Nígbà tí mo rí àlàáfíà àwọn ẹni burúkú.+ Òwe 23:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kí ọkàn rẹ má ṣe jowú àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀,+Àmọ́ kí o máa bẹ̀rù Jèhófà láti àárọ̀ ṣúlẹ̀,+