Jeremáyà 15:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ìwọ fúnra rẹ mọ̀, Jèhófà,Rántí mi kí o sì kíyè sí mi. Gbẹ̀san mi lára àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi.+ Má ṣe jẹ́ kí n ṣègbé* torí o kì í tètè bínú. O ṣáà mọ̀ pé nítorí rẹ ni mo ṣe ń fara da ẹ̀gàn yìí.+ 2 Kọ́ríńtì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 wọ́n ṣe inúnibíni sí wa, àmọ́ a ò pa wá tì;+ wọ́n gbé wa ṣánlẹ̀, àmọ́ a ò pa run.+ 2 Pétérù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+
15 Ìwọ fúnra rẹ mọ̀, Jèhófà,Rántí mi kí o sì kíyè sí mi. Gbẹ̀san mi lára àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi.+ Má ṣe jẹ́ kí n ṣègbé* torí o kì í tètè bínú. O ṣáà mọ̀ pé nítorí rẹ ni mo ṣe ń fara da ẹ̀gàn yìí.+
9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+