-
Ẹ́sítà 7:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Torí náà, wọ́n gbé Hámánì kọ́ sórí òpó igi tó ṣe fún Módékáì, ìbínú ọba sì rọlẹ̀.
-
-
Sáàmù 7:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ó ti wa kòtò, ó sì gbẹ́ ẹ jìn,
Àmọ́ ó já sínú ihò tí òun fúnra rẹ̀ gbẹ́.+
-