-
Ẹ́sítà 7:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Torí náà, wọ́n gbé Hámánì kọ́ sórí òpó igi tó ṣe fún Módékáì, ìbínú ọba sì rọlẹ̀.
-
-
Sáàmù 35:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nítorí pé wọ́n ti dẹ àwọ̀n dè mí láìnídìí;
Wọ́n ti gbẹ́ kòtò fún mi* láìnídìí.
-
-
Sáàmù 57:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Wọ́n ti gbẹ́ kòtò dè mí,
Àmọ́ àwọn fúnra wọn kó sínú rẹ̀.+ (Sélà)
-
-
Òwe 26:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ẹni tó gbẹ́ kòtò yóò já sínú rẹ̀,
Ẹni tó bá sì yí òkúta kúrò, òkúta náà yóò pa dà sórí rẹ̀.+
-