Sáàmù 16:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 O jẹ́ kí n mọ ọ̀nà ìyè.+ Ayọ̀ púpọ̀+ wà ní iwájú* rẹ,Ìdùnnú* sì wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ títí láé.