Sáàmù 121:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kò ní jẹ́ kí ẹsẹ̀ rẹ yọ̀.*+ Ẹni tó ń ṣọ́ ọ kò ní tòògbé láé.