Ẹ́sítà 5:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Hámánì wá ń fọ́nnu nípa ọlá ńlá rẹ̀, bí àwọn ọmọ rẹ̀+ ṣe pọ̀ tó, bí ọba ṣe gbé e ga àti bó ṣe gbé e lékè àwọn ìjòyè àti àwọn ìránṣẹ́ ọba.+ Jóòbù 21:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí ló dé tí àwọn ẹni burúkú ṣì fi wà láàyè,+Tí wọ́n ń darúgbó, tí wọ́n sì ń di ọlọ́rọ̀?*+
11 Hámánì wá ń fọ́nnu nípa ọlá ńlá rẹ̀, bí àwọn ọmọ rẹ̀+ ṣe pọ̀ tó, bí ọba ṣe gbé e ga àti bó ṣe gbé e lékè àwọn ìjòyè àti àwọn ìránṣẹ́ ọba.+