Sáàmù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn èèyàn burúkú kò rí bẹ́ẹ̀;Wọ́n dà bí ìyàngbò* tí afẹ́fẹ́ ń gbá lọ. Òwe 10:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìrántí* olódodo yẹ fún ìbùkún,+Àmọ́ orúkọ àwọn ẹni burúkú yóò jẹrà.+ 2 Pétérù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+
9 Torí náà, Jèhófà* mọ bó ṣe ń gba àwọn èèyàn tó ń sìn ín tọkàntọkàn sílẹ̀ lọ́wọ́ àdánwò,+ síbẹ̀ ó mọ bó ṣe máa fi àwọn aláìṣòdodo pa mọ́ de ìparun* ní ọjọ́ ìdájọ́,+