Sáàmù 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà yóò di ibi ààbò* fún àwọn tí à ń ni lára,+Ibi ààbò ní àkókò wàhálà.+ Àìsáyà 33:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà, ṣojúure sí wa.+ Ìwọ la gbẹ́kẹ̀ lé. Di apá* wa+ ní àràárọ̀,Àní, ìgbàlà wa ní àkókò wàhálà.+