-
Dáníẹ́lì 3:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Tó bá rí bẹ́ẹ̀, ìwọ ọba, Ọlọ́run wa tí à ń sìn lè gbà wá sílẹ̀ kúrò nínú iná ìléru tó ń jó, ó sì lè gbà wá sílẹ̀ lọ́wọ́ rẹ.+
-
-
Dáníẹ́lì 6:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Inú ọba dùn gan-an, ó sì pàṣẹ pé kí wọ́n gbé Dáníẹ́lì jáde kúrò nínú ihò náà. Nígbà tí wọ́n gbé Dáníẹ́lì jáde kúrò nínú ihò náà, kò fara pa rárá, torí pé ó gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run rẹ̀.+
-