Sáàmù 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ṣojú rere sí mi,* Jèhófà, nítorí ó ti ń rẹ̀ mí. Wò mí sàn, Jèhófà,+ nítorí àwọn egungun mi ń gbọ̀n. Sáàmù 41:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mo sọ pé: “Jèhófà, ṣojú rere sí mi.+ Wò mí* sàn,+ torí mo ti ṣẹ̀ sí ọ.”+ Sáàmù 51:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jẹ́ kí n gbọ́ ìró ayọ̀ àti ti ìdùnnú,Kí àwọn egungun mi tí ìwọ ti fọ́ lè máa yọ̀.+
2 Ṣojú rere sí mi,* Jèhófà, nítorí ó ti ń rẹ̀ mí. Wò mí sàn, Jèhófà,+ nítorí àwọn egungun mi ń gbọ̀n.