Sáàmù 39:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mi ò lè sọ̀rọ̀, ṣe ni mo dákẹ́;+Mi ò sọ nǹkan kan, kódà nípa ohun rere,Síbẹ̀, ìrora mi le kọjá sísọ.* Sáàmù 39:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Mi ò lè sọ̀rọ̀;Mi ò lè la ẹnu mi,+Nítorí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni.+
2 Mi ò lè sọ̀rọ̀, ṣe ni mo dákẹ́;+Mi ò sọ nǹkan kan, kódà nípa ohun rere,Síbẹ̀, ìrora mi le kọjá sísọ.*