Jóòbù 40:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Wò ó! Mi ò já mọ́ nǹkan kan.+ Kí ni màá fi dá ọ lóhùn? Mo fi ọwọ́ bo ẹnu mi.+ Sáàmù 38:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́, màá ṣe bí adití, mi ò ní fetí sí wọn;+Màá ṣe bí ẹni tí kò lè sọ̀rọ̀, mi ò ní la ẹnu mi.+