Sáàmù 62:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Èémí lásán ni àwọn ọmọ èèyàn,Ẹ̀tàn ni àwọn ọmọ aráyé.+ Tí a bá gbé gbogbo wọn lórí òṣùwọ̀n, wọ́n fúyẹ́ ju èémí lásán.+ Sáàmù 144:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Èèyàn dà bí èémí lásán;+Àwọn ọjọ́ rẹ̀ dà bí òjìji tó ń kọjá lọ.+
9 Èémí lásán ni àwọn ọmọ èèyàn,Ẹ̀tàn ni àwọn ọmọ aráyé.+ Tí a bá gbé gbogbo wọn lórí òṣùwọ̀n, wọ́n fúyẹ́ ju èémí lásán.+