Léfítíkù 25:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ ta ilẹ̀ náà títí láé,+ torí tèmi ni ilẹ̀ náà.+ Ojú àjèjì àti àlejò ni mo fi ń wò yín.+ 1 Kíróníkà 29:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nítorí àjèjì àti àlejò ni a jẹ́ níwájú rẹ, bí gbogbo àwọn baba ńlá wa ti jẹ́.+ Nítorí àwọn ọjọ́ wa lórí ilẹ̀ ayé da bí òjìji,+ kò sí ìrètí kankan.
23 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ ta ilẹ̀ náà títí láé,+ torí tèmi ni ilẹ̀ náà.+ Ojú àjèjì àti àlejò ni mo fi ń wò yín.+
15 Nítorí àjèjì àti àlejò ni a jẹ́ níwájú rẹ, bí gbogbo àwọn baba ńlá wa ti jẹ́.+ Nítorí àwọn ọjọ́ wa lórí ilẹ̀ ayé da bí òjìji,+ kò sí ìrètí kankan.