Sáàmù 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní tèmi, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé;+Àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ yóò máa mú ọkàn mi yọ̀.+