ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 37:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Jèhófà+

      Kí o sì dúró* dè é.

      Má banú jẹ́ nítorí ẹni

      Tó gbèrò ibi, tó sì mú un ṣẹ.+

  • Ìdárò 3:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Mo* sọ pé, “Jèhófà ni ìpín mi,+ ìdí nìyẹn tí màá ṣe fi sùúrù dúró dè é.”+

  • Míkà 7:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Àmọ́ ní tèmi, èmi yóò máa retí Jèhófà.+

      Màá dúró* de Ọlọ́run ìgbàlà mi.+

      Ọlọ́run mi yóò gbọ́ mi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́