1 Sámúẹ́lì 17:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Dáfídì fún Filísínì náà lésì pé: “Ìwọ ń mú idà àti ọ̀kọ̀ àti ẹ̀ṣín*+ bọ̀ wá bá mi jà, ṣùgbọ́n èmi ń bọ̀ wá bá ọ ní orúkọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,+ Ọlọ́run ìlà ogun Ísírẹ́lì, ẹni tí o pẹ̀gàn.*+ Sáàmù 20:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn kan gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ẹṣin, àwọn míì sì gbẹ́kẹ̀ lé ẹṣin,+Àmọ́, àwa ń ké pe orúkọ Jèhófà Ọlọ́run wa.+ Sáàmù 33:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ọ̀pọ̀ ọmọ ogun kọ́ ló ń gba ọba là;+Agbára ńlá kò sì lè gba ẹni tó ni ín sílẹ̀.+
45 Dáfídì fún Filísínì náà lésì pé: “Ìwọ ń mú idà àti ọ̀kọ̀ àti ẹ̀ṣín*+ bọ̀ wá bá mi jà, ṣùgbọ́n èmi ń bọ̀ wá bá ọ ní orúkọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,+ Ọlọ́run ìlà ogun Ísírẹ́lì, ẹni tí o pẹ̀gàn.*+
7 Àwọn kan gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ẹṣin, àwọn míì sì gbẹ́kẹ̀ lé ẹṣin,+Àmọ́, àwa ń ké pe orúkọ Jèhófà Ọlọ́run wa.+