ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 139:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 139 Jèhófà, o ti yẹ̀ mí wò látòkè délẹ̀, o sì mọ̀ mí.+

  • Oníwàásù 12:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nítorí Ọlọ́run tòótọ́ yóò dá àwọn èèyàn lẹ́jọ́ lórí gbogbo ohun tí wọ́n ṣe, títí kan gbogbo ohun tó fara pa mọ́, bóyá ó dára tàbí ó burú.+

  • Jeremáyà 17:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Èmi, Jèhófà, ń wá inú ọkàn,+

      Mo sì ń ṣàyẹ̀wò èrò inú,*

      Kí n lè san èrè fún ẹnì kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà rẹ̀

      Àti gẹ́gẹ́ bí èso iṣẹ́ rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́