Ìfihàn 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ìràwọ̀ méje wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀,+ idà olójú méjì,+ tó mú, tó sì gùn yọ jáde láti ẹnu rẹ̀, ìrísí ojú rẹ̀ sì dà bí oòrùn tó ń mú ganrín-ganrín.+ Ìfihàn 19:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Idà tó mú, tó sì gùn jáde láti ẹnu rẹ̀,+ kó lè fi pa àwọn orílẹ̀-èdè, ó sì máa fi ọ̀pá irin ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn.+ Bákan náà, ó ń tẹ ìbínú àti ìrunú Ọlọ́run Olódùmarè níbi tí a ti ń fún wáìnì.+
16 Ìràwọ̀ méje wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀,+ idà olójú méjì,+ tó mú, tó sì gùn yọ jáde láti ẹnu rẹ̀, ìrísí ojú rẹ̀ sì dà bí oòrùn tó ń mú ganrín-ganrín.+
15 Idà tó mú, tó sì gùn jáde láti ẹnu rẹ̀,+ kó lè fi pa àwọn orílẹ̀-èdè, ó sì máa fi ọ̀pá irin ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn.+ Bákan náà, ó ń tẹ ìbínú àti ìrunú Ọlọ́run Olódùmarè níbi tí a ti ń fún wáìnì.+