Àìsáyà 32:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Wò ó! Ọba+ kan máa jẹ fún òdodo,+Àwọn ìjòyè sì máa ṣàkóso fún ìdájọ́ òdodo.