Jóṣúà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ṣebí mo ti pàṣẹ fún ọ? Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, má sì jáyà, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ.”+ Jeremáyà 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sì dájú pé wọ́n á bá ọ jà,Ṣùgbọ́n wọn kò ní borí* rẹ,Nítorí ‘mo wà pẹ̀lú rẹ + láti gbà ọ́’ ni Jèhófà wí.” Róòmù 8:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Kí ni ká wá sọ sọ́rọ̀ yìí? Tí Ọlọ́run bá wà lẹ́yìn wa, ta ló lè dènà wa?+
9 Ṣebí mo ti pàṣẹ fún ọ? Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, má sì jáyà, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ.”+
19 Ó sì dájú pé wọ́n á bá ọ jà,Ṣùgbọ́n wọn kò ní borí* rẹ,Nítorí ‘mo wà pẹ̀lú rẹ + láti gbà ọ́’ ni Jèhófà wí.”