Sáàmù 48:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nínú àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò,Ọlọ́run ti jẹ́ kí a mọ̀ pé òun ni ibi ààbò.*+ Sáàmù 125:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí àwọn òkè ṣe yí Jerúsálẹ́mù ká,+Bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà yí àwọn èèyàn rẹ̀ ká+Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé.
2 Bí àwọn òkè ṣe yí Jerúsálẹ́mù ká,+Bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà yí àwọn èèyàn rẹ̀ ká+Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé.