Sáàmù 89:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Ta ló wà láàyè tí kò ní kú?+ Ṣé ó lè gba ara* rẹ̀ lọ́wọ́ agbára Isà Òkú ni?* (Sélà)