-
Jóòbù 30:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Torí mo mọ̀ pé wàá mú kí n kú,
Kí n lọ sí ibi tí gbogbo alààyè á ti pàdé.
-
-
Sáàmù 49:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Kò sí ìkankan nínú wọn tó lè ra arákùnrin kan pa dà
Tàbí tí ó lè fún Ọlọ́run ní ìràpadà nítorí rẹ̀,+
-