1 Sámúẹ́lì 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà ń pani, ó sì ń dá ẹ̀mí ẹni sí;*Ó múni sọ̀ kalẹ̀ lọ sínú Isà Òkú,* ó sì ń gbéni dìde.+ Jóòbù 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Bí ìkùukùu tó ń pa rẹ́ lọ, tó sì wá pòórá,Ẹni tó lọ sí Isà Òkú* kì í pa dà wá.+