ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 21:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 wọ́n sì sọ fún un pé: “Ṣé o gbọ́ ohun tí àwọn yìí ń sọ?” Jésù sọ fún wọn pé: “Bẹ́ẹ̀ ni. Ṣé ẹ ò kà á rí pé, ‘Láti ẹnu àwọn ọmọdé àti àwọn ọmọ jòjòló lo ti mú kí ìyìn jáde’?”+

  • Lúùkù 10:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ní wákàtí yẹn gan-an, ó yọ̀ gidigidi nínú ẹ̀mí mímọ́, ó sì sọ pé: “Baba, Olúwa ọ̀run àti ayé, mo yìn ọ́ ní gbangba, torí pé o rọra fi àwọn nǹkan yìí pa mọ́ fún àwọn ọlọ́gbọ́n àti àwọn amòye,+ o sì ti ṣí wọn payá fún àwọn ọmọdé. Bẹ́ẹ̀ ni, Baba, torí pé ohun tí o fọwọ́ sí nìyí.+

  • 1 Kọ́ríńtì 1:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 àmọ́, Ọlọ́run yan àwọn ohun òmùgọ̀ ayé, kí ó lè dójú ti àwọn ọlọ́gbọ́n; Ọlọ́run sì yan àwọn ohun aláìlera ayé, kí ó lè dójú ti àwọn ohun tó lágbára;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́