1 Kọ́ríńtì 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nítorí ó wà lákọsílẹ̀ pé: “Màá mú kí ọgbọ́n àwọn ọlọ́gbọ́n ṣègbé, làákàyè àwọn amòye ni màá sì kọ̀ sílẹ̀.”*+ 1 Kọ́ríńtì 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní báyìí, àwa ń sọ̀rọ̀ ọgbọ́n láàárín àwọn tó dàgbà nípa tẹ̀mí,+ àmọ́ kì í ṣe ọgbọ́n ètò àwọn nǹkan yìí* tàbí ti àwọn alákòóso ètò àwọn nǹkan yìí, àwọn tó máa di asán.+
19 Nítorí ó wà lákọsílẹ̀ pé: “Màá mú kí ọgbọ́n àwọn ọlọ́gbọ́n ṣègbé, làákàyè àwọn amòye ni màá sì kọ̀ sílẹ̀.”*+
6 Ní báyìí, àwa ń sọ̀rọ̀ ọgbọ́n láàárín àwọn tó dàgbà nípa tẹ̀mí,+ àmọ́ kì í ṣe ọgbọ́n ètò àwọn nǹkan yìí* tàbí ti àwọn alákòóso ètò àwọn nǹkan yìí, àwọn tó máa di asán.+