-
Sáàmù 69:30, 31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Màá kọ orin ìyìn sí orúkọ Ọlọ́run,
Màá sì fi ọpẹ́ gbé e ga.
31 Èyí máa mú inú Jèhófà dùn ju akọ màlúù,
Ju akọ ọmọ màlúù tó ní ìwo àti pátákò.+
-
-
Òwe 21:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Kí èèyàn ṣe ohun tó dára tí ó sì tọ́
Máa ń mú inú Jèhófà dùn ju ẹbọ lọ.+
-