Diutarónómì 23:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Tí o bá jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ má ṣe lọ́ra láti san án.+ Torí ó dájú pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa béèrè rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ; àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ó máa di ẹ̀ṣẹ̀ sí ọ lọ́rùn.+ Sáàmù 76:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, kí ẹ sì san án,+Kí gbogbo àwọn tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ mú ẹ̀bùn wọn wá pẹ̀lú ìbẹ̀rù.+ Oníwàásù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbàkigbà tí o bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Ọlọ́run, má fi falẹ̀, san án,+ nítorí inú rẹ̀ kì í dùn sí àwọn òmùgọ̀.+ Ohun tí o jẹ́jẹ̀ẹ́, san án.+
21 “Tí o bá jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ má ṣe lọ́ra láti san án.+ Torí ó dájú pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa béèrè rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ; àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ó máa di ẹ̀ṣẹ̀ sí ọ lọ́rùn.+
11 Ẹ jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, kí ẹ sì san án,+Kí gbogbo àwọn tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ mú ẹ̀bùn wọn wá pẹ̀lú ìbẹ̀rù.+
4 Nígbàkigbà tí o bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Ọlọ́run, má fi falẹ̀, san án,+ nítorí inú rẹ̀ kì í dùn sí àwọn òmùgọ̀.+ Ohun tí o jẹ́jẹ̀ẹ́, san án.+