-
Sáàmù 9:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Àwọn èèyàn burúkú á sá pa dà, wọ́n á sì forí lé Isà Òkú,*
Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tó gbàgbé Ọlọ́run.
-
-
Hósíà 4:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 A ó pa àwọn èèyàn mi lẹ́nu mọ́,* torí pé wọn kò ní ìmọ̀.
-