2 Sámúẹ́lì 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kí ló dé tí o kò fi ka ọ̀rọ̀ Jèhófà sí, tí o wá ṣe ohun tó burú lójú rẹ̀? O fi idà pa+ Ùráyà ọmọ Hétì! Lẹ́yìn náà, o sọ ìyàwó rẹ̀ di tìrẹ+ lẹ́yìn tí o ti mú kí idà àwọn ọmọ Ámónì pa á.+ Sáàmù 38:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Mo jẹ́wọ́ àṣìṣe mi;+Ẹ̀ṣẹ̀ mi dààmú mi.+
9 Kí ló dé tí o kò fi ka ọ̀rọ̀ Jèhófà sí, tí o wá ṣe ohun tó burú lójú rẹ̀? O fi idà pa+ Ùráyà ọmọ Hétì! Lẹ́yìn náà, o sọ ìyàwó rẹ̀ di tìrẹ+ lẹ́yìn tí o ti mú kí idà àwọn ọmọ Ámónì pa á.+