-
Sáàmù 36:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Ẹ̀ṣẹ̀ jinlẹ̀ lọ́kàn ẹni burúkú;
Kò sí ìbẹ̀rù Ọlọ́run lójú rẹ̀.+
-
-
Sáàmù 36:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ó máa ń gbèrò ibi, kódà lórí ibùsùn rẹ̀.
Ọ̀nà tí kò dáa ló forí lé;
Kì í kọ ohun búburú sílẹ̀.
-