-
Lúùkù 15:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ó sì máa ń wù ú kó jẹ èèpo èso kárọ́ọ̀bù tí àwọn ẹlẹ́dẹ̀ ń jẹ, àmọ́ ẹnì kankan kì í fún un ní ohunkóhun.