Òwe 27:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ọmọ mi, jẹ́ ọlọ́gbọ́n, kí o sì mú ọkàn mi yọ̀,+Kí n lè fún ẹni tó ń pẹ̀gàn mi lésì.+