Òwe 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Òwe Sólómọ́nì.+ Ọlọ́gbọ́n ọmọ ń mú inú bàbá rẹ̀ dùn,+Àmọ́ òmùgọ̀ ọmọ ń kó ẹ̀dùn ọkàn bá ìyá rẹ̀. Òwe 23:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọmọ mi, tí ọkàn rẹ bá gbọ́n,Ọkàn tèmi náà á yọ̀.+ 2 Jòhánù 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Inú mi dùn gan-an torí mo rí lára àwọn ọmọ rẹ tó ń rìn nínú òtítọ́,+ bí Baba ṣe pa á láṣẹ fún wa.