Òwe 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọlọ́gbọ́n ọmọ máa ń gba ẹ̀kọ́ bàbá rẹ̀,+Àmọ́ ẹlẹ́gàn kì í fetí sí ìbáwí.*+ Òwe 27:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ọmọ mi, jẹ́ ọlọ́gbọ́n, kí o sì mú ọkàn mi yọ̀,+Kí n lè fún ẹni tó ń pẹ̀gàn mi lésì.+