Léfítíkù 19:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘O ò gbọ́dọ̀ máa bani lórúkọ jẹ́ káàkiri láàárín àwọn èèyàn rẹ.+ O ò gbọ́dọ̀ dìde lòdì sí ẹ̀mí* ẹnì kejì rẹ.*+ Èmi ni Jèhófà. Òwe 20:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Abanijẹ́ ń sọ ọ̀rọ̀ àṣírí kiri;+Má ṣe bá ẹni tó fẹ́ràn láti máa ṣòfófó* kẹ́gbẹ́. Òwe 26:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ọ̀rọ̀ abanijẹ́ dà bí òkèlè dídùn;*Tí a gbé mì sínú ikùn lọ́hùn-ún.+
16 “‘O ò gbọ́dọ̀ máa bani lórúkọ jẹ́ káàkiri láàárín àwọn èèyàn rẹ.+ O ò gbọ́dọ̀ dìde lòdì sí ẹ̀mí* ẹnì kejì rẹ.*+ Èmi ni Jèhófà.