Sáàmù 18:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ìwọ jẹ́ mímọ́ sí ẹni tí ó mọ́,+Àmọ́ ìwọ ń jẹ́ kí àwọn oníbékebèke mọ̀ pé òmùgọ̀ ni wọ́n.+ Òwe 3:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Nítorí Jèhófà kórìíra oníbékebèke,+Ṣùgbọ́n àwọn adúróṣinṣin ni ọ̀rẹ́ Rẹ̀ tímọ́tímọ́.+