1 Àwọn Ọba 21:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ó dájú pé kò sí ẹni tó dà bí Áhábù,+ ẹni tó ti pinnu* láti máa ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà, ẹni tí Jésíbẹ́lì+ ìyàwó rẹ̀ ń tì gbọ̀n-ọ́n gbọ̀n-ọ́n.
25 Ó dájú pé kò sí ẹni tó dà bí Áhábù,+ ẹni tó ti pinnu* láti máa ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà, ẹni tí Jésíbẹ́lì+ ìyàwó rẹ̀ ń tì gbọ̀n-ọ́n gbọ̀n-ọ́n.