Òwe 29:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Gbogbo bí ọ̀rọ̀ ṣe rí lára* òmùgọ̀ ló máa ń sọ jáde,+Àmọ́ ọlọ́gbọ́n máa ń mú sùúrù.+