Òwe 16:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọ̀rọ̀ dídùn jẹ́ afárá oyin,Ó dùn mọ́ ọkàn,* ó sì ń wo egungun sàn.+ Àìsáyà 50:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti fún mi ní ahọ́n àwọn tí a kọ́,*+Kí n lè mọ bó ṣe yẹ kí n fi ọ̀rọ̀ tó yẹ* dá ẹni tó ti rẹ̀ lóhùn.*+ Ó ń jí mi ní àràárọ̀;Ó ń jí etí mi kí n lè fetí sílẹ̀ bí àwọn tí a kọ́.+
4 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti fún mi ní ahọ́n àwọn tí a kọ́,*+Kí n lè mọ bó ṣe yẹ kí n fi ọ̀rọ̀ tó yẹ* dá ẹni tó ti rẹ̀ lóhùn.*+ Ó ń jí mi ní àràárọ̀;Ó ń jí etí mi kí n lè fetí sílẹ̀ bí àwọn tí a kọ́.+