-
Sáàmù 39:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Màá fi ìbonu bo ẹnu mi+
Ní gbogbo ìgbà tí ẹni burúkú bá wà níwájú mi.”
-
-
Sáàmù 141:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Jèhófà, jọ̀wọ́ yan ẹ̀ṣọ́ fún ẹnu mi,
Kí o sì máa ṣọ́ ilẹ̀kùn ètè mi.+
-